Olababs delivered another hit song titled ”Anu Mo Bere”. Speaking about the song, Olababs says “the song is a prayer song, seeking for the mercy of God to live a successful and fulfilled life here on earth and also make heaven, to reign with God.”
LYRICS
CHORUS:
Anu ni mo bere, baba sanu fun mi,
Mo teriba nibi eje Jesu nsan
Ma se je ki Ijoba Orun bo sonu lowo mi,
Eyi ni mofe, Jesu sanu fun mi
VERSE 1:
Emi yoo gboju mi sori oke wonni
Nibo n’iranlowo mi yo ha ti wa
Iranlowo mi at’owo Olorun wa o
Olorun anu, baba sanu fun mi,
Ere kini o je fun e arakunrin
Ko jogun aye, ko so emi re nu u,
Ma se mi l’adorun mo otito
Mo be o baba,
K’oun aye yi ma gba ijoba orun lowo mi
Repeat Chorus
VERSE 2:
Nipase anu, Jabezi d’olorire,
Nipa se anu, serah diya orile ede,
Mo gbeke le o o,
Dakun sanu fun mi
Eni gbekele o ki ma I jogun ofo,
Obinrin onisun eje ori anu gba
Logan nisun eje odun mejila gbe,
Sanu fun mi,
Maje n sa ko bata fegbe o
Karaye ma bi mi wipe olorun mi da
Repeat Chorus
HYMN:
Bugbe re ti le wa to nile mole ati fe (2x)
Okan mi fani tooto, fun idapo eyan re,
Fun imole oju re, fun ekun re olorun.
More Stories
AUDIO: Wealthy Breed – Debacle (Mp3 Download)
AUDIO: Helen Meju – Thank You (Mp3 Download)
AUDIO: Ekerete Jackson BOEKOM – Lambano {Mp3 Download}