AUDIO: Ope Gold – Ipe Mi (Mp3 Download)

Ope Gold delivered another hit single track titled ”Ipe Mi”. Enjoy your day with the amazing sound.
LYRICS:
CHORUS:
Olorun ma je n sope danu
Oluwa ma je n fipe sofo
Ki n le sare ije mi lasala..
Ki n gba kaabo omo odorere
VERSE 1
Ebun nikan o to lati satona ipe
Tori ebun atipe ohun oto loje
O leni ebun sugbon ki o ma gba ipe
Birarewo nje mogba ipe ni
Ooto ni pe a pe o o kilo n fise
Dagaru gbaboru nikan nipe tire
Sora kina re ma baa dokunkun iwo ti a gba dide fun telomiran
VERSE 2
Sora fun pepe ti o ti n gbadura
Owo o si fun pepe mo bi tigbakan
Isefefe asan ati sekarimi o
Loku ninu ijo baba GBE wa dide
Ifarahan ogo a maa mupe dagba
Katowi ki a to fo onigbowo a de
Ailegbadura a maa muni sina
Ka ma ba a gba ogo sonu laye re
VERSE 3
Dakun wa o jeka soro isiti
Matori owo so ipe re nu o
Matori owo firo bo ooto mole
Tori ojo kan nbo to ni se a de
Masese lara ipe bolorun soro o
O damiloju wipe koni salai gbo
Fi gbagbo sope ipe mi a dide o
Tori iranwo orun a dide fun o
Call: Ipe mi a dide a si fohun ka gbogbo agbaye ja
Resp: Orimi LA o GBE soke maa saseye loruko jesu
Call: Ipemi o ni di tan un o ni tan o ki n to tan baba
Call: Ipe mi a dide a si fohun ka gbogbo agbaye ja
Call: Opin re ni ka de orun ka si gba kaabo omo odo rere
Call: Mase kan ju ola o ninu ipe re okan ni kogbala o