Ope Gold

Ope Gold – Ipe Mi

Sharing would be really nice!!!

Ope Gold delivered another hit single track titled ”Ipe Mi”. Enjoy your day with the amazing sound. http://www.godlikitchen.com/wp-content/uploads/2021/02/Ope-Gold-Ipe-Mi.mp3 DOWNLOAD AUDIO LYRICS: CHORUS: Olorun ma je n sope danu Oluwa ma je n fipe sofo Ki n le sare ije mi lasala.. Ki n gba kaabo omo odorere VERSE 1 Ebun nikan o to lati satona ipe Tori ebun atipe ohun oto loje O leni ebun sugbon ki o ma gba